Work

Ipa Ètò Yorùbá lórí Rédíò Lágelú pa Kík Ará- Ìlú ní Èdè àti À à Yorùbá: Ìwòye àw n Olùgb Mélòó kan ní Ìbàdàn

Year: 2019
Type: article
Study design: Observational Study
Abstract: Lára e ko -ilé tí a máa ń fún ọmọ ní ile Yorùbá ni bí a ṣe ń lo èdè tàbí so ro ní àwùjọ pe lú àwọn ìṣe àti ìhùwàsí Yorùbá tó sodo sínú àṣà wọn. Èyí ló máa ń mú kí wo n bá àwùjọ mu, kí ètò sì wà láàrin ìlú. Àmo ṣá, ìrírí wa lóde-òní ni pé o po ilé ló ti sọ èdè àti àṣà Yorùbá nù. Èyí sì ti pagidínà ètò àti ìwà ọmọlúàbí ní àwùjọ. Láti gbé èdè àti àṣà Yorùbá lárugẹ, o po ilé-iṣe rédíò aládàáni ni àwọn olùfe èdè àti àṣà Yorùbá ti dá síle . O kan gbògíì sì ni ilé-iṣe rédíò Lágelú ní Ìbàdàn je nínú wọn. Látàrí èyí, iṣe yìí wádìí ìwòye àwọn olùgbo nípa ipa tí ètò Yorùbá lórí rédíò Lágelú ń kó nínú kíko ará ìlú ní èdè àti àṣà Yorùbá, nípa gígùnlé tío rì Ìfàkíyèsínímo àti tío rì Ìgbo kànlé. Ìfo ro wánile nuwò ni a ṣe fún àwọn olùgbo me fà àti ato kùn ètò Yorùbá me ta tí a mo o nmo yàn fún iṣe yìí. A tún fetí sí àwọn ètò me te e ta náà (Oríkì Ile Wa, Láwùjọ Àgbà àti Tiwa N Tiwa) ní àìmọye ìgbà kí á lè ṣe àfiwé ìwòye àwọn olùgbo àti àkíyèsí wa nípa àkóónú àwọn ètò náà. Àbo ìwádìí yìí fi hàn pé bí ó tile je pé àwọn ètò náà ń ko ni ní ìlò-èdè Yorùbá, wo n ì ń ṣe àfihàn àti ìgbélárugẹ àṣà Yorùbá, àwọn àṣìlò-èdè àti àṣà bíi mélòó, tí ó lè ṣí ará-ilú lo kàn, ń úyọ. Ó yẹ kí wo n mójútó èyí bí wọn bá fe kí àfojúsùn wọn nípa gbígbé èdè àti àṣà Yorùbá lárugẹ wá sí ìmúṣẹ.
Language: Yoruba
Open Access status: green
OpenAlex ID: W7154589540
FWCI: 0.574
Cites:
Cited by: 1
Related to: 10